
Mike Ifabunmi Arẹmu, to jẹ ogbontarigi ọmọ Brazil to kọṣẹ mọṣẹ lori Ifa kíkì bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ lórí pàtàkì Ifá gẹgẹ bii òrìṣà to ju awon oriṣa lọ.
O sọ nipa bí òun ṣe kọ ifá nilẹ Yoruba ati bi ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ àti ẹ̀sìn ìmàle ti àwọn oyinbo mu wa Brazil ṣe n pa ẹ̀sìn ìbílẹ̀ lára lásìkò yìí.
O ki oríkì ifá gẹgẹ bii ọrọ ti Ọrunmila sọ jáde lẹnu.
- ‘Mu ọti nilu Ilọrin, ko ri ẹwọn he’
- ‘A fẹ́ kí ìjọba dá ẹjọ́ yìí dáadáa kí Ochanya lè sùn lọ́run’
- Ọta ara ni ọti lile
- BBC ṣe’filọlẹ Yoruba, Igbo ati Pidgin
- Iceland n fẹ fagile abẹ dida
- Orilẹede ti ko fẹran ayajọ ọjọ ololufẹ
Ifabunmi ki odù Ògúndábèbe láti fidi ẹ mulẹ pé agbára Olodumare pọ̀, O dẹ̀ maa n ṣe ohun to wuu ni nipa ṣiṣe ọkan bi Ọyẹ́, òmíràn bíi otútù, kí a to sọ ọ̀dá àti òjò.
O ni Naijiria ti di ìlú òun keji nitori pe ìlú Ibadan, to jẹ olú ìlú ipinlẹ Ọyọ nipinlẹ oun ti oun ti maa n wa foribalẹ fun oriṣa oun.
O ni fasiti Ibadan ni oun ti kọ ẹ̀kọ́ kikun nipa èdè ati àṣà.
- ‘Kò sí ǹkan tí o kò lè ṣe tóo bá ní àfojúsùn’
- ‘Ọ̀rẹ́ mi ní kí n fi ‘acid’ sí oúnjẹ ọmọ mi’
- ‘Mo máa ń ṣa ìdọ̀tí kúrò lójú omi láti dóòlà ẹ̀mí ìjàpá ni’
Erreur
Cette vidéo n’existe pas
